April 26–May 2
NỌ́ŃBÀ 25-26
Orin 135 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Nọ 26:55, 56—Báwo ni ọ̀nà tí Jèhófà gbà pín ogún fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi hàn pé ọlọ́gbọ́n ni Jèhófà? (it-1 359 ¶1-2)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 25:1-18 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò kan kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 3)
Àsọyé: (5 min.) w04 4/1 29—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Iye Èèyàn Tí Nọ́ńbà 25:9 Sọ Pé Ó Kú Fi Yàtọ̀ Sí Iye Tí 1 Kọ́ríńtì 10:8 Sọ? (th ẹ̀kọ́ 17)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Fọgbọ́n Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Tó Jẹ́ Àríkọ́gbọ́n fún Wa—Àyọlò. Rọ àwọn ará pé kí wọ́n lọ wo gbogbo fídíò náà látòkèdélẹ̀.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr apá kẹta, orí 8 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 8
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 44 àti Àdúrà