ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 14
  • Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Sọ Ègún Di Ìbùkún
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bí Ìgbàgbọ́ Ṣe Lè Jẹ́ Ká Nígboyà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní

Àwọn ọmọ Móábù mú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì dẹ́ṣẹ̀ (Nọ 25:​1, 2; lv 97 ¶1-2)

Inú Jèhófà ò dùn sáwọn ọmọ Ísírẹ́lì torí pé wọ́n di aláìṣòótọ́, wọ́n sì mọ tara wọn nìkan (Nọ 25:​3-5; lv 98 ¶4)

Ìbínú Jèhófà rọlẹ̀ torí pé ẹnì kan fi ìgboyà gbé ìgbésẹ̀ (Nọ 25:​6-11)

Ọ̀dọ́bìnrin kan ń ṣàlàyé ohun tó wà nínú ìwé ‘Origin of Life’ fáwọn ọmọ kíláàsì rẹ̀. Ọ̀kan lára àwọn ọmọ kíláàsì nawọ́ sókè.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn nǹkan wo ló ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀ tá gba pé kí n jẹ́ onígboyà kí n sì yàtọ̀ sáwọn tó kù?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́