ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 May ojú ìwé 10-11
  • June 10-16

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 10-16
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 May ojú ìwé 10-11

JUNE 10-16

SÁÀMÙ 48-50

Orin 126 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Fọkàn Tán Ètò Jèhófà

(10 min.)

Ẹ ran àwọn ọmọ yín lọ́wọ́ kí wọ́n lè sún mọ́ Jèhófà àti ètò rẹ̀ (Sm 48:12, 13; w22.03 22 ¶11; w11 3/15 19 ¶5-7)

Máa sọ àwọn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ nínú ètò Ọlọ́run fún àwọn ọmọ rẹ (w12 8/15 12 ¶5)

Tó o bá ń ṣe ohun tí ètò Jèhófà sọ, á rọrùn fún àwọn ọmọ rẹ láti ṣe bẹ́ẹ̀ (Sm 48:14)

Àwòrán: 1. Baba kan ń bá ọmọ ẹ̀ sọ̀rọ̀, ó sì tọ́ka sí ìwé “A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà.” 2. Ìdílé kan ń wo ètò Tẹlifíṣọ̀n JW. 3. Ìdílé míì ṣèbẹ̀wò sí ọ̀kan lára àwọn ibi àfihàn wa ní Bẹ́tẹ́lì. 4. Ìyá kan ń lo “Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà” àti ìwé “Jehovah’s Witnesses—Proclaimers of God’s Kingdom” láti kọ́ ọmọ ẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́.

OHUN TẸ́ Ẹ LÈ ṢE NÍGBÀ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ: Lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, ẹ máa wo àwọn fídíò tó wà ní abala “Ètò wa” lórí ìkànnì jw.org, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 49:6, 7—Kí ló yẹ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi sọ́kàn nípa ọrọ̀ tí wọ́n ní? (it-2 805)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 50:1-23 (th ẹ̀kọ́ 11)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Jẹ́ Onígboyà—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 6 kókó 1-2.

5. Jẹ́ Onígboyà—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 6 kókó 3-5 àti “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 73

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 11 ¶1-4, ọ̀rọ̀ ìṣáájú apá 4, àti àwọn àpótí ojú ìwé 86-87

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 103 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́