ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 November ojú ìwé 3
  • November 11-17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 11-17
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 November ojú ìwé 3

NOVEMBER 11-17

SÁÀMÙ 106

Orin 36 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Wọ́n Gbàgbé Ọlọ́run Olùgbàlà Wọn”

(10 min.)

Nígbà tí ẹ̀rù ba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà (Ẹk 14:11, 12; Sm 106:7-9)

Nígbà tí òùngbẹ ń gbẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, tí ebi sì ń pa wọ́n, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kùn sí Jèhófà (Ẹk 15:24; 16:3, 8; 17:2, 3; Sm 106:13, 14)

Nígbà tí ọkàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò balẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í jọ́sìn òrìṣà (Ẹk 32:1; Sm 106:19-21; w18.07 20 ¶13)

Arábìnrin kan fẹ́ lọ wàásù, ó sì ń ronú nípa àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà ràn án lọ́wọ́ sẹ́yìn. Àwòrán: 1. Àwọn alàgbà bẹ̀ ẹ́ wò láti fún un níṣìírí. 2. Ẹnì kan gbé báàgì tí oúnjẹ kún inú ẹ̀ fún un. 3. Ọ̀rẹ́ ẹ̀ kan fi lẹ́tà àti fọ́tò ránṣẹ́ sí i.

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Tá a bá níṣòro, kí nìdí tó fi dáa ká máa ronú nípa àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà ràn wá lọ́wọ́ láwọn ìgbà kan rí?

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 106:36, 37—Tẹ́nì kan bá ń jọ́sìn òrìṣà, ṣé a lè sọ pé irú ẹni bẹ́ẹ̀ ń rúbọ sáwọn ẹ̀mí èṣù? (w06 7/15 13 ¶9)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 106:21-48 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Kọ́ni Lọ́nà Tó Rọrùn—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 11 kókó 1-2.

5. Kọ́ni Lọ́nà Tó Rọrùn—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 11 kókó 3-5 àti apá “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 78

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 18 ¶1-5, àwọn àpótí ojú ìwé 142, 144

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 77 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́