JUNE 2-8
ÒWE 16
Orin 36 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Ìbéèrè Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Lè Ṣèpinnu Tó Dáa
(10 min.)
Ṣé mo gbà pé ìmọ̀ràn Jèhófà ló dáa jù fún mi? (Owe 16:3, 20; w14 1/15 19-20 ¶11-12)
Ṣé ìpinnu yìí máa múnú Jèhófà dùn? (Owe 16:7)
Ṣé kì í ṣe ohun táwọn èèyàn ń ṣe àti ohun tí wọ́n ń sọ ló fẹ́ mú kí n ṣèpinnu yìí? (Owe 16:25; w13 9/15 17 ¶1-3)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo làwọn ìbéèrè yìí ṣe lè jẹ́ kí n ṣèpinnu tó dáa tó bá dọ̀rọ̀ ìmúra mi?’
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Owe 16:1-20 (th ẹ̀kọ́ 12)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Jẹ́ kí ẹnì kan rí bí ìkànnì jw.org ṣe lè ṣe é láǹfààní. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 5)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. O ti fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà nígbà kan rí, àmọ́ kò gbà. Gbìyànjú láti tún fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ̀ ọ́. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 5)
6. Àsọyé
(5 min.) ijwbv àpilẹ̀kọ 40—Àkòrí: Kí Ni Ìtumọ̀ Òwe 16:3? (th ẹ̀kọ́ 8)
Orin 32
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 27 ¶10-18