JUNE 23-29
ÒWE 19
Orin 154 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Àtàtà Sáwọn Ará
(10 min.)
Máa gbójú fo àwọn àṣìṣe wọn (Owe 19:11; w23.11 12-13 ¶16-17)
Máa ràn wọ́n lọ́wọ́ nígbà ìṣòro (Owe 19:17; w23.07 9-10 ¶10-11)
Máa fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí wọn (Owe 19:22; w21.11 9 ¶6-7)
ÀPÈJÚWE: Bó ṣe jẹ́ pé èyí tó bá dáa nínú àwọn fọ́tò tá a bá yà la máa ń tọ́jú, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe yẹ kó jẹ́ pé àwọn ìwà àti ìṣe tó dáa táwọn ará wa ní ló yẹ ká máa rántí.
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Owe 19:1-20 (th ẹ̀kọ́ 2)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Wá ọ̀nà tó o lè gbà jẹ́ kẹ́ni náà mọ̀ pé Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni ẹ́ láìjẹ́ pé o mẹ́nu ba ọ̀rọ̀ Bíbélì. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 4)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Nígbà tẹ́ ẹ jọ sọ̀rọ̀ kẹ́yìn, ẹni náà sọ fún ẹ pé òun fẹ́ràn láti máa wo àwọn nǹkan tí Ọlọ́run dá. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 4)
6. Àsọyé
(5 min.) lmd àfikún A kókó 10—Àkòrí: Ọlọ́run Ní Orúkọ. (th ẹ̀kọ́ 20)
Orin 40
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 28 ¶1-7