OCTOBER 27–NOVEMBER 2
ONÍWÀÁSÙ 11-12
Orin 155 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Ohun Tó Máa Jẹ́ Kó O Láyọ̀, Kó O sì Ní Ìlera Tó Dáa
(10 min.)
Tó bá ṣeé ṣe, máa wáyè ṣeré jáde kó o lè gbádùn afẹ́fẹ́ tó tura (Onw 11:7, 8; w23.03 25 ¶16)
Má ṣe máa ronú jù, kó o sì máa tọ́jú ara ẹ (Onw 11:10; w23.02 21 ¶6-7)
Èyí tó ṣe pàtàkì jù ni pé kó o máa fi gbogbo ọkàn ẹ sin Jèhófà (Onw 12:13; w24.09 2 ¶2-3)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Onw 12:10—Ṣé òótọ́ lohun tó wà nínú Bíbélì àbí ìtàn àròsọ lásán ni? (lff ẹ̀kọ́ 3 kókó 1)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Onw 12:1-14 (th ẹ̀kọ́ 12)
4. Pa Dà Lọ
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. (lmd ẹ̀kọ́ 8 kókó 3)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Nígbà tẹ́ ẹ jọ sọ̀rọ̀ kẹ́yìn, ẹni náà sọ fún ẹ pé èèyàn òun kan kú. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)
6. Àsọyé
(5 min.) lmd àfikún A kókó 13—Àkòrí: Ọlọ́run Múra Tán Láti Ràn Wá Lọ́wọ́. (th ẹ̀kọ́ 20)
Orin 111
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 30-31