DECEMBER 1-7
ÀÌSÁYÀ 3-5
Orin 135 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Jèhófà Retí Pé Káwọn Èèyàn Òun Máa Ṣègbọràn sí Òun
(10 min.)
Jèhófà fara balẹ̀ ‘gbin ọgbà àjàrà’ rẹ̀, ó sì retí pé kó méso jáde (Ais 5:1, 2, 7; ip-1 73-74 ¶3-5; 76 ¶8-9)
Àjàrà igbó nìkan ni ọgbà àjàrà Jèhófà mú jáde (Ais 5:4; w06 6/15 18 ¶1)
Jèhófà sọ pé òun máa sọ ọgbà àjàrà náà di ahoro (Ais 5:5, 6; w06 6/15 18 ¶2)
BI ARA RẸ PÉ: ‘Báwo ni ìtàn yìí ṣe lè ràn mí lọ́wọ́ láti yẹra fún àwọn nǹkan tí inú Jèhófà ò dùn sí?’
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Ais 5:8, 9—Kí làwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe tó bí Jèhófà nínú? (ip-1 80 ¶18-19)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Ais 5:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi fídíò kan látinú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ han ẹnì kan, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 5)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Sọ fún ẹni náà nípa JW Library, kó o sì bá a wà á sórí fóònù ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 5)
6. Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn
(5 min.) Fún ẹni tó ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì níṣìírí torí pé àwọn tó wà nínú ìdílé ẹ̀ ń ta kò ó. (lmd ẹ̀kọ́ 12 kókó 4)
Orin 65
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 40-41