DECEMBER 29, 2025–JANUARY 4, 2026
ÀÌSÁYÀ 14-16
Orin 63 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Ọ̀tá Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Ò Ní Lọ Láìjìyà
(10 min.)
Jèhófà máa pa Bábílónì tó jẹ́ agbéraga run, kò sì ní gbérí mọ́ láé (Ais 14:13-15, 22, 23; ip-1 180 ¶16; 184 ¶24)
Jèhófà máa fọ́ àwọn ará Ásíríà túútúú ní ilẹ̀ rẹ̀ (Ais 14:24, 25; ip-1 189 ¶1)
Jèhófà máa dójú ti Móábù (Ais 16:13, 14; ip-1 194 ¶12)
Òsì: C. Sappa/DeAgostini via Getty Images; ọ̀tún: Image © Homo Cosmicos/Shutterstock
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Ais 14:1, 2—Báwo làwọn èèyàn Jèhófà ṣe “mú àwọn tó mú wọn lẹ́rú”? (w06 12/1 11 ¶1)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Ais 16:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 5)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 4)
6. Àsọyé
(5 min.) ijwbq àpilẹ̀kọ 108—Àkòrí: Kí Ni Àsọtẹ́lẹ̀? (th ẹ̀kọ́ 14)
Orin 2
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 48-49