Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Ọlọ́run Dáhùn Àdúrà Obìnrin Afọ́jú Kan
Mingjie gbàdúrà pé kí Ọlọ́run jẹ́ kóun pàdé àwọn Kristẹni tòótọ́. Kí ló jẹ́ kó dá a lójú pé Ọlọ́run ti dáhùn àdúrà yẹn?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ > WỌ́N Ń KỌ́NI NÍ ÒTÍTỌ́ BÍBÉLÌ.
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
Ṣé Èèyàn Àlàáfíà àti Kristẹni Tòótọ́ Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní New Zealand?
Lọ́dún 1940 sí 1949, kí nìdí tí wọ́n fi kéde pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ta ko ìjọba àti pé èèyàn eléwu ni wá?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA.