Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
NOVEMBER 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JANUARY 3-30, 2022
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Rúùtù wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Náómì ìyá ọkọ ẹ̀, Ọ́pà sì ń pa dà sí Móábù. Rúùtù sọ fún Náómì pé: “Ibi tí o bá lọ ni èmi yóò lọ” (Wo àpilẹ̀kọ 45, ìpínrọ̀ 13)