Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 44: January 3-9, 2022
2 Báwo Ni Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì Í Yẹ̀ Ṣe Ń Ṣe Ọ́ Láǹfààní?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 45: January 10-16, 2022
8 Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn sí Ara Yín
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 46: January 17-23, 2022
14 Ẹ̀yin Tẹ́ Ẹ Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ṣègbéyàwó, Ẹ Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 47: January 24-30, 2022
20 Ṣé O Ní Ìgbàgbọ́ Tó Lágbára Tó?
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Mò Ń Wá Bí Mo Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Tó Dáa
31 Ǹjẹ́ O Mọ̀?—Kí ló ṣẹlẹ̀ sí ìlú Nínéfè lẹ́yìn ìgbà ayé Jónà?