Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí 2
Àwọn ohun pàtàkì tó ṣẹlẹ̀ lọ́dún tó kọjá 6
A Fún Iṣẹ́ Ìwàásù Kárí Ayé Láfiyèsí 11
“Ẹ̀yin Ni Aládùúgbò Tó Dáa Jù Lọ” 16
Ìpàdé Tuntun fún Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni 19
Ètò Orí Tẹlifíṣọ̀n JW Ń ‘Fún Wa Lókun, Ó sì Ń Mára Tù Wá!’ 24
À Ń Wàásù A sì Ń Kọ́ni Kárí Ayé 46
Éṣíà àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn Ayé 61
Àwọn Tó Ń Wá Òtítọ́ Láyé Ìgbà Kan 89
Ìpàdé Mú Kí Ìgbàgbọ́ Gbogbo Wọn Lágbára 97
Mo Bẹ Jèhófà Pé Kó Tọ́ Mi Sọ́nà 106
‘Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe Lọ́dọ̀ Ọlọ́run’ 108
“Ọlọ́run Ń Mú Kí Ó Máa Dàgbà.”—1 Kọ́r. 3:6. 111
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Onífẹ̀ẹ́ Ṣètò Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ 118
Ọkọ Mi Ò Ṣíwọ́ Kíka Bíbélì! 128
Mò Ń Wò Ó Pé Ayé Mi Ti Dáa 132
Ìfẹ́ Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Kì Í Yẹ̀ 134
Mo Fojú Ara Mi Rí Ohun tí Bíbélì Sọ! 136
Wọ́n Rí Ìbùkún ‘ní Àsìkò tí Ó Rọgbọ àti ní Àsìkò tí Ó Kún fún Ìdààmú.’—2 Tím. 4:2. 138
Wọ́n Ń Sin Jèhófà, Bí Ọ̀tá Tiẹ̀ Ń Gbógun 145
“Èyí Ni Ohun Ìní Àjogúnbá Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà.”—Aísá. 54:17. 157
Wọ́n Rántí Ẹlẹ́dàá Wọn Atóbilọ́lá 162
Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Kurdish Gba Ẹ̀kọ́ Òtítọ́ 169
Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn—1917 172
Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn 2016 ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé 178