B12-A
Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)
Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀
Tẹ́ńpìlì
Ọgbà Gẹ́tísémánì (?)
Ààfin Gómìnà
Ilé Káyáfà (?)
Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?)
Adágún Omi Bẹtisátà
Adágún Omi Sílóámù
Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?)
Gọ́gọ́tà (?)
Ákélídámà (?)
Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 8 | Nísàn 9 | Nísàn 10 | Nísàn 11
Nísàn 8 (Sábáàtì)
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)
Ó dé sí Bẹ́tánì lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú ọjọ́ Ìrékọjá
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 9
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Ó bá Símónì adẹ́tẹ̀ jẹun
Màríà da òróró náádì sí Jésù lórí
Àwọn Júù wá wo Jésù àti Lásárù
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ
Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 10
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Ó sun Bẹ́tánì mọ́jú
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Ìrìn àjò ní kùtùkùtù sí Jerúsálẹ́mù
Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́
Jèhófà sọ̀rọ̀ látọ̀run
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 11
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì, ó lo àpèjúwe
Ó dẹ́bi fún àwọn Farisí
Ó kíyè sí ọrẹ tí opó kan ṣe
Lórí Òkè Ólífì, ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ ìparun Jerúsálẹ́mù àti àmì ìgbà tó máa wà níhìn-ín