ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 8-9
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà fún Ìrántí Ikú Kristi ti Ọdún 2023

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà fún Ìrántí Ikú Kristi ti Ọdún 2023
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • WEDNESDAY, MARCH 29
  • THURSDAY, MARCH 30
  • FRIDAY, MARCH 31
  • SATURDAY, APRIL 1
  • SUNDAY, APRIL 2
  • MONDAY, APRIL 3
  • TUESDAY, APRIL 4
  • ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (LẸ́YÌN TÍ OÒRÙN BÁ WỌ̀)
  • WEDNESDAY, APRIL 5
  • THURSDAY, APRIL 6
  • FRIDAY, APRIL 7
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà fún Ìrántí Ikú Kristi Ti Ọdún 2022
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà fún Ìrántí Ikú Kristi ti Ọdún 2025
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Lásìkò Ìrántí Ikú Kristi Ọdún 2024
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
  • B12-B Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 8-9
Jésù ń gbé òpó igi oró tí wọ́n máa kàn án mọ́.

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà Fún Ìrántí Ikú Kristi Ti Ọdún 2023

WEDNESDAY, MARCH 29

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 8 bẹ̀rẹ̀)

THURSDAY, MARCH 30

Màríà ń da òróró olóòórùn dídùn sórí Jésù bó ṣe wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ tábìlì.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 9 bẹ̀rẹ̀)

Jésù​—Ọ̀nà, orí 101

FRIDAY, MARCH 31

Jésù wà lórí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ nígbà táwọn èrò tínú wọn ń dùn ń tẹ́ aṣọ àti imọ̀ ọ̀pẹ sílẹ̀ lójú ọ̀nà.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

Jésù​—Ọ̀nà, orí 102

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 10 bẹ̀rẹ̀)

SATURDAY, APRIL 1

Jésù ń dojú tábìlì àwọn tó ń ṣẹ́ owó dé nínú tẹ́ńpìlì.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

Jésù​—Ọ̀nà, orí 103 àti 104

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 11 bẹ̀rẹ̀)

SUNDAY, APRIL 2

Jésù àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ ń wo opó aláìní kan bó ṣe ń ju owó kéékèèké méjì sínú àpótí ìṣúra nínú tẹ́ńpìlì.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

Jésù​—Ọ̀nà, orí 105 sí 114

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 12 bẹ̀rẹ̀)

MONDAY, APRIL 3

Júdásì Ìsìkáríọ́tù ń gbìmọ̀ pẹ̀lú àwọn aṣáájú ẹ̀sìn. Owó ẹyọ fàdákà tí wọ́n dà sílẹ̀.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

Jésù​—Ọ̀nà, orí 115

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 13 bẹ̀rẹ̀)

TUESDAY, APRIL 4

ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (LẸ́YÌN TÍ OÒRÙN BÁ WỌ̀)

Jésù àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ olóòótọ́ jọ wà nídìí tábìlì nígbà Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 14 bẹ̀rẹ̀)

Jésù​—Ọ̀nà, orí 116 sí 126

WEDNESDAY, APRIL 5

Jésù wà lórí òpó igi oró, ọ̀daràn kan sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

Jésù​—Ọ̀nà, orí 127 sí 133

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 15 bẹ̀rẹ̀)

THURSDAY, APRIL 6

Àwọn aṣáájú ẹ̀sìn ń béèrè ohun tí wọ́n fẹ́ lọ́wọ́ Pọ́ńtíù Pílátù.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 16 bẹ̀rẹ̀)

FRIDAY, APRIL 7

Obìnrin mẹ́ta ń wo inú ibojì Jésù, àmọ́ kò sí nǹkan kan níbẹ̀.

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

Jésù​—Ọ̀nà, orí 134 àti 135

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Nísàn 17 bẹ̀rẹ̀)

Àwòrán ilẹ̀ Jerúsálẹ́mù àti àwọn agbègbè tó wà nítòsí rẹ̀. Orúkọ àwọn ibi táwọn èèyàn mọ̀ àtàwọn ibi tó ṣeé ṣe kó jẹ́. 1. Tẹ́ńpìlì. 2. Ọgbà Gẹ́tísémánì. 3. Ààfin gómìnà. 4. Ilé Káyáfà. 5. Ààfin tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà lò. 6. Odò Bẹtisátà. 7. Odò Sílóámù. 8. Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn. 9. Gọ́gọ́tà. 10. Ákélídámà.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́