B12-B
Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)
Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀
Tẹ́ńpìlì
Ọgbà Gẹ́tísémánì (?)
Ààfin Gómìnà
Ilé Káyáfà (?)
Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?)
Adágún Omi Bẹtisátà
Adágún Omi Sílóámù
Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?)
Gọ́gọ́tà (?)
Ákélídámà (?)
Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 12 | Nísàn 13 | Nísàn 14 | Nísàn 15 | Nísàn 16
Nísàn 12
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ wà níbi tó pa rọ́rọ́
Júdásì ṣètò bí wọ́n ṣe máa mú Jésù
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 13
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Pétérù àti Jòhánù múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá
Jésù àtàwọn àpọ́sítélì yòókù dé ní ọjọ́rọ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 14
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Òun àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ jẹ Ìrékọjá
Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì
Ó ní kí Júdásì máa lọ
Ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀
Nísàn 15 (Sábáàtì)
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Pílátù gbà pé kí wọ́n fi àwọn ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ sàréè Jésù
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 16
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
Ó jíǹde
Ó fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn