LÉFÍTÍKÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
3
4
5
Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ pàtó àti ọrẹ tí ẹni tó ṣẹ̀ máa mú wá (1-6)
Ọrẹ tí àwọn aláìní máa mú wá (7-13)
Ẹbọ ẹ̀bi fún ẹ̀ṣẹ̀ àìmọ̀ọ́mọ̀dá (14-19)
6
7
Ìtọ́ni nípa àwọn ọrẹ (1-21)
Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ọ̀rá tàbí ẹ̀jẹ̀ (22-27)
Ìpín àlùfáà (28-36)
Ọ̀rọ̀ ìparí nípa àwọn ọrẹ (37, 38)
8
9
10
Iná bọ́ látọ̀dọ̀ Jèhófà, ó sì pa Nádábù àti Ábíhù (1-7)
Ìlànà tí àwọn àlùfáà yóò máa tẹ̀ lé nípa jíjẹ àti mímu (8-20)
11
12
13
14
15
16
17
Àgọ́ ìjọsìn, ibi tí wọ́n ti ń rúbọ (1-9)
Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ (10-14)
Ìlànà nípa àwọn ẹran tó ti kú (15, 16)
18
19
20
Ìjọsìn Mólékì; ìbẹ́mìílò (1-6)
Ẹ jẹ́ mímọ́ kí ẹ sì bọ̀wọ̀ fún àwọn òbí (7-9)
Ikú tọ́ sí àwọn oníṣekúṣe (10-21)
Ẹ jẹ́ mímọ́ kí ẹ lè wà ní ilẹ̀ náà (22-26)
Ikú tọ́ sí àwọn abẹ́mìílò (27)
21
Kí àwọn àlùfáà jẹ́ mímọ́ kí wọ́n má sì di ẹlẹ́gbin (1-9)
Àlùfáà àgbà ò gbọ́dọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ (10-15)
Àwọn àlùfáà ò gbọ́dọ̀ ní àbùkù kankan lára (16-24)
22
23
24
25
Ọdún Sábáàtì (1-7)
Ọdún Júbílì (8-22)
Dídá ohun ìní pa dà (23-34)
Bí ẹ ṣe máa ṣe sí aláìní (35-38)
Òfin nípa ìfiniṣẹrú (39-55)
26
27
Ríra ohun téèyàn jẹ́jẹ̀ẹ́ rẹ̀ pa dà (1-27)
Àwọn ohun téèyàn yà sọ́tọ̀ pátápátá fún Jèhófà (28, 29)
Ríra ìdá mẹ́wàá pa dà (30-34)