1 SÁMÚẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ẹlikénà àti àwọn ìyàwó rẹ̀ (1-8)
Hánà tó jẹ́ àgàn gbàdúrà kó lè rọ́mọ bí (9-18)
Ó bí Sámúẹ́lì, ó sì fi í fún Jèhófà (19-28)
2
3
4
5
6
7
Àpótí náà dé Kiriati-jéárímù (1)
Sámúẹ́lì rọ̀ wọ́n pé: ‘Ẹ sin Jèhófà nìkan ṣoṣo’ (2-6)
Ísírẹ́lì ṣẹ́gun ní Mísípà (7-14)
Sámúẹ́lì ṣe onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì (15-17)
8
9
10
11
12
13
Sọ́ọ̀lù yan àwọn ọmọ ogun (1-4)
Sọ́ọ̀lù kọjá àyè rẹ̀ (5-9)
Sámúẹ́lì bá Sọ́ọ̀lù wí (10-14)
Ísírẹ́lì kò ní àwọn ohun ìjà (15-23)
14
Àṣeyọrí tí Jónátánì ṣe ní Míkímáṣì (1-14)
Ọlọ́run lé àwọn ọ̀tá Ísírẹ́lì lọ (15-23)
Ẹ̀jẹ́ tí Sọ́ọ̀lù jẹ́ láìronú jinlẹ̀ (24-46)
Àwọn ogun tí Sọ́ọ̀lù jà; ìdílé rẹ̀ (47-52)
15
Àìgbọ́ràn mú kí Sọ́ọ̀lù dá Ágágì sí (1-9)
Sámúẹ́lì bá Sọ́ọ̀lù wí (10-23)
Ọlọ́run kọ Sọ́ọ̀lù lọ́ba (24-29)
Sámúẹ́lì pa Ágágì (30-35)
16
Sámúẹ́lì fòróró yan Dáfídì láti jọba lẹ́yìn Sọ́ọ̀lù (1-13)
Ẹ̀mí Ọlọ́run kúrò lára Sọ́ọ̀lù (14-17)
Dáfídì di ẹni tó ń ta háàpù fún Sọ́ọ̀lù (18-23)
17
18
Dáfídì àti Jónátánì di ọ̀rẹ́ (1-4)
Sọ́ọ̀lù ń jowú torí pé Dáfídì ń ṣẹ́gun (5-9)
Sọ́ọ̀lù gbìyànjú láti pa Dáfídì (10-19)
Dáfídì fẹ́ Míkálì ọmọ Sọ́ọ̀lù (20-30)
19
20
21
22
Dáfídì ní Ádúlámù àti Mísípè (1-5)
Sọ́ọ̀lù ní kí wọ́n pa àwọn àlùfáà tó wà ní Nóbù (6-19)
Ábíátárì sá àsálà (20-23)
23
Dáfídì gba ìlú Kéílà sílẹ̀ (1-12)
Sọ́ọ̀lù lépa Dáfídì (13-15)
Jónátánì fún Dáfídì lókun (16-18)
Díẹ̀ ló kù kí ọwọ́ Sọ́ọ̀lù tẹ Dáfídì (19-29)
24
25
Ikú Sámúẹ́lì (1)
Nábálì kan àwọn ọkùnrin Dáfídì lábùkù (2-13)
Ábígẹ́lì hùwà ọgbọ́n (14-35)
Jèhófà kọ lu Nábálì tó jẹ́ òmùgọ̀ (36-38)
Ábígẹ́lì di ìyàwó Dáfídì (39-44)
26
27
28
29
30
Àwọn ọmọ Ámálékì wá kó ẹrù ní Síkílágì, wọ́n sì dáná sun ún (1-6)
Dáfídì ṣẹ́gun àwọn ọmọ Ámálékì (7-31)
Dáfídì gba àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú pa dà (18, 19)
Ìlànà tí Dáfídì fi lélẹ̀ lórí pípín ẹrù ogun (23, 24)
31