ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 431-432
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Sámúẹ́lì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Sámúẹ́lì
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wàhálà Nínú Ilé Dáfídì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Sámúẹ́lì Kejì
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Gbára Lé Ẹ̀mí Ọlọ́run Nígbà Tí Ipò Nǹkan Bá Yí Padà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
Àwọn Míì
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Sámúẹ́lì

2 SÁMÚẸ́LÌ

OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ

  • 1

    • Dáfídì gbọ́ nípa ikú Sọ́ọ̀lù (1-16)

    • Orin arò tí Dáfídì kọ nítorí Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì (17-27)

  • 2

    • Dáfídì di ọba Júdà (1-7)

    • Íṣí-bóṣétì di ọba Ísírẹ́lì (8-11)

    • Ogun tó wáyé láàárín ilé Dáfídì àti ilé Sọ́ọ̀lù (12-32)

  • 3

    • Ilé Dáfídì ń di alágbára sí i (1)

    • Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì (2-5)

    • Ábínérì lọ dara pọ̀ mọ́ Dáfídì (6-21)

    • Jóábù pa Ábínérì (22-30)

    • Dáfídì ṣọ̀fọ̀ Ábínérì (31-39)

  • 4

    • Wọ́n pa Íṣí-bóṣétì (1-8)

    • Dáfídì ní kí wọ́n pa àwọn apààyàn náà (9-12)

  • 5

    • Dáfídì di ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì (1-5)

    • Wọ́n gba Jerúsálẹ́mù (6-16)

      • Síónì, Ìlú Dáfídì (7)

    • Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì (17-25)

  • 6

    • Wọ́n gbé Àpótí náà wá sí Jerúsálẹ́mù (1-23)

      • Úsà gbá Àpótí náà mú, ó sì kú (6-8)

      • Míkálì pẹ̀gàn Dáfídì (16, 20-23)

  • 7

    • Dáfídì kò ní lè kọ́ tẹ́ńpìlì (1-7)

    • Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú ìjọba (8-17)

    • Àdúrà ìdúpẹ́ tí Dáfídì gbà (18-29)

  • 8

    • Àwọn tí Dáfídì ṣẹ́gun (1-14)

    • Ìjọba Dáfídì (15-18)

  • 9

    • Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí Dáfídì ní sí Méfíbóṣétì (1-13)

  • 10

    • Ó ṣẹ́gun Ámónì àti Síríà (1-19)

  • 11

    • Dáfídì àti Bátí-ṣébà ṣe àgbèrè (1-13)

    • Dáfídì ṣètò pé kí wọ́n pa Ùráyà (14-25)

    • Dáfídì fi Bátí-ṣébà ṣe aya (26, 27)

  • 12

    • Nátánì bá Dáfídì wí (1-15a)

    • Ọmọ Bátí-ṣébà kú (15b-23)

    • Bátí-ṣébà bí Sólómọ́nì (24, 25)

    • Dáfídì gba ìlú Rábà tó jẹ́ ti àwọn ọmọ Ámónì (26-31)

  • 13

    • Ámínónì fipá bá Támárì lò pọ̀ (1-22)

    • Ábúsálómù pa Ámínónì (23-33)

    • Ábúsálómù sá lọ sí Géṣúrì (34-39)

  • 14

    • Jóábù àti obìnrin ará Tèkóà (1-17)

    • Dáfídì já ọgbọ́nkọ́gbọ́n Jóábù (18-20)

    • Dáfídì gbà kí Ábúsálómù pa dà (21-33)

  • 15

    • Ọ̀tẹ̀ àti rìkíṣí tí Ábúsálómù dì (1-12)

    • Dáfídì sá kúrò ní Jerúsálẹ́mù (13-30)

    • Áhítófẹ́lì dara pọ̀ mọ́ Ábúsálómù (31)

    • Ọba rán Húṣáì láti ta ko Áhítófẹ́lì (32-37)

  • 16

    • Síbà sọ̀rọ̀ Méfíbóṣétì láìdáa (1-4)

    • Ṣíméì gbé Dáfídì ṣépè (5-14)

    • Ábúsálómù gba Húṣáì sọ́dọ̀ (15-19)

    • Ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì (20-23)

  • 17

    • Húṣáì sọ ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì di asán (1-14)

    • Wọ́n kìlọ̀ fún Dáfídì; ó bọ́ lọ́wọ́ Ábúsálómù (15-29)

      • Básíláì àti àwọn míì pèsè oúnjẹ (27-29)

  • 18

    • Wọ́n ṣẹ́gun Ábúsálómù, wọ́n sì pa á (1-18)

    • Dáfídì gbọ́ nípa ikú Ábúsálómù (19-33)

  • 19

    • Dáfídì ṣọ̀fọ̀ Ábúsálómù (1-4)

    • Jóábù bá Dáfídì wí (5-8a)

    • Dáfídì pa dà sí Jerúsálẹ́mù (8b-15)

    • Ṣíméì tọrọ ìdáríjì (16-23)

    • Méfíbóṣétì fi hàn pé òun ò ṣẹ̀ (24-30)

    • Básíláì gbayì (31-40)

    • Àríyànjiyàn láàárín àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì (41-43)

  • 20

    • Ṣébà dìtẹ̀; Jóábù pa Ámásà (1-13)

    • Wọ́n lépa Ṣébà, wọ́n sì gé orí rẹ̀ (14-22)

    • Ìjọba Dáfídì (23-26)

  • 21

    • Àwọn ará Gíbíónì gbẹ̀san lára ilé Sọ́ọ̀lù (1-14)

    • Àwọn ogun tó wáyé láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn Filísínì (15-22)

  • 22

    • Dáfídì yin Ọlọ́run nítorí ìgbàlà tí ó ṣe (1-51)

      • “Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi” (2)

      • Jèhófà jẹ́ adúróṣinṣin sí àwọn adúróṣinṣin (26)

  • 23

    • Ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ kẹ́yìn (1-7)

    • Ohun tí àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú gbé ṣe (8-39)

  • 24

    • Dáfídì dẹ́ṣẹ̀ torí pé ó ka èèyàn (1-14)

    • Àjàkálẹ̀ àrùn pa 70,000 (15-17)

    • Dáfídì mọ pẹpẹ (18-25)

      • Kò sí ẹbọ tí kì í náni ní nǹkan (24)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́