ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 657
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nehemáyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nehemáyà
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Nehemáyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Ògiri Jerúsálẹ́mù
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • “Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • “Jọ̀wọ́, Ọlọ́run Mi, Rántí Mi fún Rere”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Àwọn Míì
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nehemáyà

NEHEMÁYÀ

OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ

  • 1

    • Ìròyìn wá láti Jerúsálẹ́mù (1-3)

    • Àdúrà Nehemáyà (4-11)

  • 2

    • Ọba rán Nehemáyà sí Jerúsálẹ́mù (1-10)

    • Nehemáyà yẹ ògiri ìlú náà wò (11-20)

  • 3

    • Wọ́n tún ògiri náà kọ́ (1-32)

  • 4

    • Àtakò kò dá iṣẹ́ náà dúró (1-14)

    • Àwọn òṣìṣẹ́ tó mú ohun ìjà dání ń bá iṣẹ́ ìkọ́lé náà lọ (15-23)

  • 5

    • Nehemáyà fòpin sí ìwà ìrẹ́jẹ (1-13)

    • Nehemáyà kò mọ tara rẹ̀ nìkan (14-19)

  • 6

    • Àtakò lórí iṣẹ́ àtúnkọ́ náà kò dáwọ́ dúró (1-14)

    • Ọjọ́ 52 ni wọ́n fi parí ògiri náà (15-19)

  • 7

    • Àwọn ẹnubodè ìlú àti àwọn aṣọ́bodè (1-4)

    • Orúkọ àwọn tó dé láti ìgbèkùn (5-69)

      • Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì (46-56)

      • Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì (57-60)

    • Ọrẹ tí wọ́n ṣe fún iṣẹ́ náà (70-73)

  • 8

    • Wọ́n ka ìwé Òfin, wọ́n sì ṣàlàyé rẹ̀ fáwọn èèyàn (1-12)

    • Wọ́n ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà (13-18)

  • 9

    • Àwọn èèyàn jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn (1-38)

      • Jèhófà, Ọlọ́run tó ń dárí jini (17)

  • 10

    • Àwọn èèyàn náà gbà láti máa pa Òfin mọ́ (1-39)

      • ‘A kò ní pa ilé Ọlọ́run wa tì’ (39)

  • 11

    • Àwọn èèyàn pa dà wá ń gbé Jerúsálẹ́mù (1-36)

  • 12

    • Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì (1-26)

    • Ayẹyẹ ṣíṣí ògiri ìlú náà (27-43)

    • Wọ́n ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ ìsìn tẹ́ńpìlì (44-47)

  • 13

    • Àwọn àtúnṣe míì tí Nehemáyà ṣe (1-31)

      • Wọ́n ní kí wọ́n mú ìdá mẹ́wàá wá (10-13)

      • Wọn ò gbọ́dọ̀ sọ Sábáàtì di aláìmọ́ (15-22)

      • Ó bẹnu àtẹ́ lu bí àwọn àtàwọn ọmọ ilẹ̀ míì ṣe ń fẹ́ra wọn (23-28)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́