ÌSÍKÍẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìsíkíẹ́lì wà ní Bábílónì, ó ń rí ìran látọ̀dọ̀ Ọlọ́run (1-3)
Ìran kẹ̀kẹ́ ẹṣin Jèhófà tó wà lọ́run (4-28)
Ìjì líle, ìkùukùu àti iná (4)
Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin (5-14)
Àgbá kẹ̀kẹ́ mẹ́rin (15-21)
Ohun kan tó tẹ́ pẹrẹsẹ, tó ń tàn yinrin bíi yìnyín (22-24)
Ìtẹ́ Jèhófà (25-28)
2
3
4
5
6
7
8
9
10
Wọ́n mú iná láàárín àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà (1-8)
Bí àwọn kérúbù àti àgbá kẹ̀kẹ́ náà ṣe rí (9-17)
Ògo Ọlọ́run kúrò ní tẹ́ńpìlì náà (18-22)
11
Ọlọ́run dá àwọn ìjòyè burúkú lẹ́jọ́ (1-13)
Ọlọ́run ṣèlérí pé wọ́n á pa dà sílé (14-21)
Ògo Ọlọ́run kúrò ní Jerúsálẹ́mù (22, 23)
Ìsíkíẹ́lì pa dà sí Kálídíà nínú ìran (24, 25)
12
13
14
15
16
17
18
19
20
Ìtàn nípa bí Ísírẹ́lì ṣe ṣọ̀tẹ̀ (1-32)
Ọlọ́run ṣèlérí pé òun yóò dá Ísírẹ́lì pa dà sórí ilẹ̀ wọn (33-44)
Sọ tẹ́lẹ̀ nípa gúúsù (45-49)
21
Ọlọ́run fa idà tó fẹ́ fi ṣèdájọ́ yọ nínú àkọ̀ (1-17)
Ọba Bábílónì máa gbéjà ko Jerúsálẹ́mù (18-24)
Ọlọ́run máa mú ìjòyè burúkú Ísírẹ́lì kúrò (25-27)
Idà yóò bá àwọn ọmọ Ámónì jà (28-32)
22
Jerúsálẹ́mù, ìlú tó jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (1-16)
Ísírẹ́lì dà bí ìdàrọ́ tí kò wúlò (17-22)
Ọlọ́run bá àwọn aṣáájú àti àwọn èèyàn Ísírẹ́lì wí (23-31)
23
24
25
Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Ámónì (1-7)
Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Móábù (8-11)
Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Édómù (12-14)
Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Filísíà (15-17)
26
27
28
Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí ọba Tírè (1-10)
Orin arò nípa ọba Tírè (11-19)
Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Sídónì (20-24)
Ọlọ́run yóò tún kó Ísírẹ́lì jọ (25, 26)
29
30
31
32
33
Iṣẹ́ olùṣọ́ (1-20)
Ìròyìn ìparun Jerúsálẹ́mù (21, 22)
Ọlọ́run rán ẹnì kan sí àwọn tó ń gbé inú àwókù (23-29)
Àwọn èèyàn ò ṣe ohun tí wọ́n gbọ́ (30-33)
34
35
36
37
38
39
Gọ́ọ̀gù àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ yóò pa run (1-10)
Wọ́n á sìnkú sí Àfonífojì Hamoni-Gọ́ọ̀gù (11-20)
Ọlọ́run yóò pa dà kó Ísírẹ́lì jọ (21-29)
40
Ọlọ́run mú Ìsíkíẹ́lì wá sí Ísírẹ́lì nínú ìran (1, 2)
Ìsíkíẹ́lì rí tẹ́ńpìlì nínú ìran (3, 4)
Àwọn àgbàlá àti àwọn ẹnubodè (5-47)
Ẹnubodè ìlà oòrùn tó wà níta (6-16)
Àgbàlá ìta; àwọn ẹnubodè míì (17-26)
Àgbàlá inú àti àwọn ẹnubodè (27-37)
Àwọn yàrá tí wọ́n ń lò fún iṣẹ́ tẹ́ńpìlì (38-46)
Pẹpẹ (47)
Ibi àbáwọlé tẹ́ńpìlì (48, 49)
41
Ibi mímọ́ tẹ́ńpìlì (1-4)
Ògiri àti àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ (5-11)
Ilé tó wà ní ìwọ̀ oòrùn (12)
Ó wọn àwọn ilé náà (13-15a)
Inú ibi mímọ́ (15b-26)
42
43
44
Ẹnubodè ìlà oòrùn yóò wà ní títì pa (1-3)
Ìlànà Ọlọ́run nípa àwọn àjèjì (4-9)
Ìlànà tí Ọlọ́run fún àwọn ọmọ Léfì àti àwọn àlùfáà (10-31)
45
Ilẹ̀ mímọ́ tí wọ́n mú wá láti fi ṣe ọrẹ àti ìlú náà (1-6)
Ilẹ̀ ìjòyè (7, 8)
Kí àwọn ìjòyè jẹ́ olóòótọ́ (9-12)
Ọrẹ tí àwọn èèyàn mú wá àti ìjòyè (13-25)
46
Àwọn ọrẹ tí wọ́n á mú wá láwọn ọjọ́ pàtàkì kan (1-15)
Ohun ìní tí ìjòyè fi ṣe ogún fúnni (16-18)
Àwọn ibi tí wọ́n á ti máa se ọrẹ (19-24)
47
48