2 TÍMÓTÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1, 2)
Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run torí ìgbàgbọ́ Tímótì (3-5)
Jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run máa jó bí iná (6-11)
Máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní (12-14)
Àwọn ọ̀tá Pọ́ọ̀lù àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ (15-18)
2
Fi ọ̀rọ̀ náà síkàáwọ́ àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n (1-7)
Jìyà nítorí ìhìn rere (8-13)
Máa lo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run bó ṣe yẹ (14-19)
Sá fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ìgbà ọ̀dọ́ (20-22)
Ohun tí o lè ṣe sí àwọn alátakò (23-26)
3
Nǹkan máa le gan-an ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn (1-7)
Tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù pẹ́kípẹ́kí (8-13)
“Má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀” (14-17)
4
“Ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan” (1-5)
“Mo ti ja ìjà rere náà” (6-8)
Àwọn ọ̀rọ̀ ara ẹni (9-18)
Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (19-22)