1 PÉTÉRÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Kí ọ̀rọ̀ náà máa wù yín (1-3)
Òkúta ààyè tí a fi kọ́ ilé tẹ̀mí (4-10)
Ẹ máa gbé bí àjèjì nínú ayé (11, 12)
Àwọn tó yẹ ká tẹrí ba fún (13-25)
3
Àwọn ọkọ àti àwọn aya (1-7)
Ẹ máa bára yín kẹ́dùn; ẹ máa wá àlàáfíà (8-12)
Tí a bá ń jìyà nítorí òdodo (13-22)
4
Ẹ ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run bíi ti Kristi (1-6)
Òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé (7-11)
Tí a bá ń jìyà torí pé a jẹ́ Kristẹni (12-19)
5