2 PÉTÉRÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Àwọn olùkọ́ èké máa wá (1-3)
Ìdájọ́ àwọn olùkọ́ èké kò ní yẹ̀ (4-10a)
Bí a ṣe lè dá àwọn olùkọ́ èké mọ̀ (10b-22)
3
Àwọn tó ń fini ṣẹlẹ́yà kò ka ìparun tó ń bọ̀ sí (1-7)
Jèhófà kì í fi nǹkan falẹ̀ (8-10)
Ẹ ronú nípa irú ẹni tó yẹ kí ẹ jẹ́ (11-16)
Ẹ ṣọ́ra kí wọ́n má bàa ṣì yín lọ́nà (17, 18)