1 TÍMÓTÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1, 2)
Ìkìlọ̀ torí àwọn olùkọ́ èké (3-11)
Inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fi hàn sí Pọ́ọ̀lù (12-16)
Ọba ayérayé (17)
‘Máa ja ogun rere’ (18-20)
2
3
Ohun tí alábòójútó gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (1-7)
Ohun tí ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (8-13)
Àṣírí mímọ́ ti ìfọkànsin Ọlọ́run (14-16)
4
Ẹ máa ṣọ́ra torí ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù (1-5)
Bí o ṣe lè jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi (6-10)
Máa kíyè sí ẹ̀kọ́ rẹ (11-16)
5
Bí o ṣe máa hùwà sí àwọn ọ̀dọ́ àtàwọn àgbà (1, 2)
Máa ran àwọn opó lọ́wọ́ (3-16)
Bọlá fún àwọn alàgbà tó ń ṣiṣẹ́ kára (17-25)
6
Kí àwọn ẹrú máa bọlá fún ọ̀gá wọn (1, 2)
Àwọn olùkọ́ èké àti ìfẹ́ owó (3-10)
Àwọn ìtọ́ni fún èèyàn Ọlọ́run (11-16)
Máa ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rere (17-19)
Máa ṣọ́ ohun tí a fi sí ìkáwọ́ rẹ (20, 21)