Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìfihàn Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
ÌFIHÀN
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìfihàn látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nípasẹ̀ Jésù ( 1-3 )
Ìkíni sí àwọn ìjọ méje ( 4-8 )
Jòhánù wà ní ọjọ́ Olúwa nípasẹ̀ ìmísí ( 9-11 )
Ìran Jésù tí a ṣe lógo ( 12-20 )
2
3
4
5
Àkájọ ìwé tó ní èdìdì méje ( 1-5 )
Ọ̀dọ́ Àgùntàn gba àkájọ ìwé náà ( 6-8 )
Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ló yẹ kó ṣí àwọn èdìdì náà ( 9-14 )
6
7
Áńgẹ́lì mẹ́rin di atẹ́gùn tó ń fa ìparun mú ( 1-3 )
A gbé èdìdì lé 144,000 ( 4-8 )
Ogunlọ́gọ̀ èèyàn wọ aṣọ funfun ( 9-17 )
8
9
10
11
12
Obìnrin náà, ọmọkùnrin náà àti dírágónì ( 1-6 )
Máíkẹ́lì bá dírágónì náà jà ( 7-12 )
Dírágónì ṣe inúnibíni sí obìnrin náà ( 13-17 )
13
Ẹranko olórí méje jáde látinú òkun ( 1-10 )
Ẹranko oníwo méjì jáde látinú ayé ( 11-13 )
Ère ẹranko olórí méje náà ( 14, 15 )
Àmì àti nọ́ńbà ẹranko náà ( 16-18 )
14
Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà àti 144,000 ( 1-5 )
Iṣẹ́ tí àwọn áńgẹ́lì mẹ́ta jẹ́ ( 6-12 )
Aláyọ̀ ni àwọn tó kú ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi ( 13 )
Wọ́n máa kórè ayé lẹ́ẹ̀mejì ( 14-20 )
15
16
17
18
“Bábílónì Ńlá” ṣubú ( 1-8 )
Wọ́n ń ṣọ̀fọ̀ ìṣubú Bábílónì ( 9-19 )
Wọ́n ń yọ̀ ní ọ̀run torí Bábílónì ṣubú ( 20 )
A máa ju Bábílónì sínú òkun bí òkúta ( 21-24 )
19
Ẹ yin Jáà, torí àwọn ìdájọ́ rẹ̀ ( 1-10 )
Ẹni tó gun ẹṣin funfun ( 11-16 )
Oúnjẹ alẹ́ ńlá ti Ọlọ́run ( 17, 18 )
A ṣẹ́gun ẹranko náà ( 19-21 )
20
A de Sátánì fún 1,000 ọdún ( 1-3 )
Àwọn tó máa jọba pẹ̀lú Kristi fún 1,000 ọdún ( 4-6 )
A tú Sátánì sílẹ̀, àmọ́ lẹ́yìn náà, a pa á run ( 7-10 )
A ṣèdájọ́ àwọn òkú níwájú ìtẹ́ náà ( 11-15 )
21
22