Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 8, 2001
Ìlera fún Gbogbo Èèyàn Ǹjẹ́ ó Ṣeé Ṣe?
Àjọ Ìlera Àgbáyé gbé góńgó “fífún gbogbo èèyàn lágbàáyé ní ìlera tó jọjú” kalẹ̀. Ṣé ọwọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìṣègùn á lè tẹ góńgó yẹn láyé ńbí?
3 Ìlera fún Gbogbo Èèyàn—Ṣé Góńgó Tó Ṣeé Lé Bá Ni?
4 Ìṣègùn Òde Òní—Ibo Lagbára Rẹ̀ mọ?
9 Ìlera fún Gbogbo Èèyàn—Láìpẹ́!
11 Bí Mo Tilẹ̀ Dití tí Mo Tún Fọ́jú, Mo Rí Ààbò
16 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
20 A Rìnrìn Àjò Lọ Sí Ọgbà Ẹranko Ní Gánà
24 Àkúnya Omi Ní—Mòsáńbíìkì Bí Àwọn Kristẹni Ṣe Bójú Tó Àwọn Tí Àjálù Náà Bá
30 Wíwo Ayé
32 Ó Ń Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Láti Kojú Ìpèníjà
Báwo Ni Mo Ṣe Le Lájọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Àwọn Òbí Mi Àgbà?
Ṣé Oríṣiríṣi Ọ̀nà Tó Lọ Sọ́dọ̀ Ọlọ́run Ni Àwọn Ìsìn Jẹ́? 28
Ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn láá dáhùn pé bẹ́ẹ̀ ni. Kí ni Bíbélì wí?