ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g01 12/8 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2001
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Oríkèé Ara Ríro Àrùn Tó Ń Sọni Di Akúrẹtẹ̀
    Jí!—2001
  • Ìrètí Ń Bẹ fún Àwọn Tó Lárùn Oríkèé-Ara-Ríro
    Jí!—2001
  • Bí Àrùn Oríkèé-ara-ríro Ṣe Máa Ń Ṣe Èèyàn
    Jí!—2001
  • Ohun Tí O Lè Sọ Nípa Àwọn Ìwé Ìròyìn
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2001
Àwọn Míì
Jí!—2001
g01 12/8 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

December 8, 2001

Ìrètí Ń Bẹ fún Àwọn Tó Lárùn Oríkèé-Ara-Ríro

Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ èèyàn, lọ́mọdé lágbà, ni àrùn oríkèé-ara-ríro ń ṣe. Kí ló ń fa àrùn tó ń sọ èèyàn di akúrẹtẹ̀ yìí? Èé ṣe táwọn tó lárùn náà fi lè fọkàn balẹ̀ pé ìtura pátápátá ń bọ̀ lọ́nà?

3 Oríkèé Ara Ríro Àrùn Tó Ń Sọni Di Akúrẹtẹ̀

5 Bí Àrùn Oríkèé-ara-ríro Ṣe Máa Ń Ṣe Èèyàn

9 Ìrètí Ń Bẹ fún Àwọn Tó Lárùn Oríkèé-Ara-Ríro

13 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

22 Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kó O Máa Kàwé Sókè Ketekete fún Ọmọ Rẹ?

25 Orúkọ Ọlọ́run Dá Àríyànjiyàn Sílẹ̀

26 Kàtídírà—Ọwọ̀n Ìrántí fún Ọlọ́run Ni àbí fún Èèyàn?

30 Wíwo Ayé

32 Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kejìlélọ́gọ́rin Ti jí!

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Tó Kún fún Ìgbàgbọ́ Látinú Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Ọlọ́jọ́ Pípẹ́ Kan 14

Ọjọ́ ti pẹ́ táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì nínú ọgbà ẹ̀wọ̀n ńlá yìí. Kí ló ti tibẹ̀ jáde?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Táwọn Oníbìínú Èèyàn Bá Kò Mí Lójú? 19

Kọ́ ohun tó o lè ṣe kó o má bàa há sọ́wọ́ ẹnì kan tó jẹ́ oníbìínú èèyàn.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́