Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 8, 2002
Ìgboyà Lákòókò Àjálù
A kọ ìwọ̀nba díẹ̀ lára àpẹẹrẹ ìwà ìgboyà, àánú àti ìfaradà táwọn èèyàn fi hàn nígbà táwọn kan kọ lu Ilé Ìtajà Tó Tóbi Jù Lọ Lágbàáyé ní September 11, 2001.
3 Ọjọ́ Lọjọ́ Tí Ilé Gogoro Méjì Wó Ní Amẹ́ríkà
10 Ìtìlẹ́yìn àti Àánú Láti Ibi Gbogbo
13 Ṣé Oúnjẹ Rẹ Kò Lè Ṣe Ọ́ Ní Jàǹbá?
18 Bí A Ṣe Lè Dín Ewu Inú Oúnjẹ Kù
21 Oúnjẹ Tí Kò Léwu Máa Wà fún Gbogbo Èèyàn
28 Wíwo Ayé
30 Ṣọ́ọ̀ṣì Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì—Ibi Ìyapa Ni
31 Ọ̀dọ́ Kan Tó Fi Ìsìn Rẹ̀ Yangàn
32 Ṣé Inú Rẹ Á Dùn Láti Rí Ìtùnú Gbà?
Ewu Wo Ló Wà Nínú Kí Àwọn Èwe Máa Dájọ́ Àjọròde? 23
Ṣé àṣà tí kò léwu nínú ni kéèyàn máa dájọ́ àjọròde? Àbí àwọn ohun kan lè tẹ̀yìn rẹ̀ jáde tó yẹ kó mú kéèyàn rò ó dáadáa kó tóó ṣe é?
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Ṣayẹyẹ Ọdún Tuntun? 26
Ibo ni ayẹyẹ Ọdún Tuntun ti ṣẹ̀ wá? Ǹjẹ́ ó ta ko ohun tí Bíbélì fi kọ́ni?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 3]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Fọ́tọ̀ AP/Matt Moyers; ojú ìwé 2 àti 3: Steve Ludlum/NYT Pictures