Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 8, 2002
Kí Làwọn Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Kọjá Lè Kọ́ Wa?
A lè kọ́ ohun tó pọ̀ nípa ọjọ́ ọ̀la látinú àwọn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá. Lọ́nà wo? Kí lọjọ́ iwájú máa mú wá?
3 Ìmọ̀ Pọ̀ Rẹpẹtẹ Àmọ́ Kò Fi Bẹ́ẹ̀ Sí Ìyípadà
4 Àwọn Orílẹ̀-Èdè Kò Tíì Kọ́gbọ́n Síbẹ̀
8 Kíkẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Kristẹni Ọ̀rúndún Kìíní
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
13 Tẹ́tẹ́ Títa—Ti Di Ohun Táwọn Èèyàn nífẹ̀ẹ́ Sí Kárí Ayé
16 Kí Ló Burú Nínú Tẹ́tẹ́ Títa?
19 Yàgò Fún Ìdẹkùn Tẹ́tẹ́ Títa
27 Ìgbọ́kànlé Tí Mo Ní Nínú Ọlọ́run Ló Mẹ́sẹ̀ Mi Dúró
32 Ó Rí Ohun Ṣíṣeyebíye Lájàalẹ̀ Ṣọ́ọ̀ṣì Kan
Irú Ojú Wo Ni Ọlọ́run Fi Ń Wo Ìwà Ipá? 22
Kí ni Bíbélì sọ nípa kókó yìí? Ìgbà wo ni Ọlọ́run máa fòpin sí ìwà ipá?
Kí Ni Mo Lè Ṣe Láti Túbọ̀ Lẹ́wà Sí I?