Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 8, 2004
Yálà O Jẹ́ Ọmọdé Tàbí Àgbàlagbà O Lè Gbádùn Ẹ̀kọ́ Kíkọ́
Ṣó o fẹ́ kí agbára tí ìwọ àtàwọn ọmọ rẹ ní láti kẹ́kọ̀ọ́ sunwọ̀n sí i? Ọ̀nà wo lo lè gbé e gbà?
3 A Dá Ìfẹ́ Láti Kẹ́kọ̀ọ́ Mọ́ Wa
4 Bá A Ṣe Lè Dẹni Tó Nífẹ̀ẹ́ sí Ẹ̀kọ́ Kíkọ́
11 A Dá Wa Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Títí Lọ Gbére
13 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
19 Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Wọ́n Lù Ọ́ Ní Jìbìtì
24 Ibo Lo Ti Lè Rí Ìwà Ọmọlúwàbí?
28 Bí Àníyàn Nípa Ìrísí Ẹni Bá Gbani Lọ́kàn Ju Bó Ṣe Yẹ Lọ
30 Aláàánú Ará Samáríà Òde Òní
31 Àwọn Ohun Ìṣeré Tó Dáa Jù Lọ Fáwọn Ọmọdé
Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Ní Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó? 14
Ó máa ń ṣe ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ bíi kí wọ́n dán ìbálòpọ̀ wò. Àmọ́, ojú wo ló yẹ kí ọ̀dọ́ kan tó jẹ́ Kristẹni fi máa wo ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó?
Ṣé Lóòótọ́ Ni Ọlọ́run Bìkítà Nípa Àwọn Ọmọdé? 26
Báwo ni Ọlọ́run yóò ṣe fòpin sí kíkó tí wọ́n ń kó àwọn ọmọdé nífà?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
© Mikkel Ostergaard/Panos Pictures