Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 8, 2002
Ǹjẹ́ Ó Léwu Láti Wọ Ọkọ̀ Òfuurufú?
Nítorí bí àwọn apániláyà ṣe ń já ọkọ̀ òfuurufú gbà, ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń béèrè pé, ‘Báwo ni ààbò tó wà nínú wíwọ ọkọ̀ òfuurufú ṣe pọ̀ tó nísinsìnyí?’
3 Ǹjẹ́ Ewu Wà—Nínú Wíwọkọ̀ Òfuurufú?
4 Bí Ọkàn Rẹ Ṣe Lè Balẹ̀ Nínú Ọkọ̀ Òfuurufú
9 Bó o Ṣe Lè Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ọ̀ràn Ààbò
18 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
19 Ìfẹ́ Fara Hàn Gbangba Níbi—Iṣẹ́ Àfiṣèrànwọ́ Kan Tó Fa Kíki
25 Eré Ìdárayá Àwọn Èwe—Ìwà Ipá Tuntun Tó Ń tàn Kálẹ̀
28 Wíwo Ayé
29 Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹtàlélọ́gọ́rin Ti jí!
30 Ilẹ̀ Gíríìsì Ti Fàyè Gba Òmìnira Ẹ̀sìn
Ṣé Bẹ́ẹ̀ Lẹ̀míi Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe Lágbára Tó Ni? 13
Ẹ̀mí ṣohun-tẹ́gbẹ́-ń-ṣe máa ń tanni jẹ—ó sì tún léwu. Kí nìdí?
Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Kérésìmesì 16
Kí ni Bíbélì sọ nípa ayẹyẹ yìí?