Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 8, 2003
Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Ilẹ̀ Amẹ́ríkà Dá Ẹ̀tọ́ Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ Padà
Àwọn adájọ́ mẹ́jọ nínú mẹ́sàn-án ló fọwọ́ sí ẹ̀tọ́ òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ, wọ́n sì sọ pé èèyàn ò ṣẹ̀ṣẹ̀ ní láti lọ gba ìwé àṣẹ lọ́dọ̀ ìjọba ìbílẹ̀ kó tó lè ní ẹ̀tọ́ yìí. Kí lohun tó sún wọn ṣe irú ìdájọ́ bẹ́ẹ̀?
4 Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Tẹ́wọ́ Gba Ẹjọ́ Náà
6 Ìgbésẹ̀ Àkọ́kọ́—Àwọn Agbẹjọ́rò Rojọ́ Níwájú Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ
9 Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Fọwọ́ Sí Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ
12 Bó O Ṣe Lè Túbọ̀ Dáàbò Bo Oyún Rẹ
21 Àdánwò Ìgbàgbọ́ ní Slovakia
28 Wíwo Ayé
30 Bí Ojú Ẹyẹ Idì Ṣe Lágbára Tó
31 ‘Àwa Ń Ṣègbọràn sí Ọlọ́run Dípò Àwọn Ènìyàn’
32 ‘Mo Padà Rí Jésù Tí a Ti Gbàgbé’
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Ẹ̀mí Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe? 15
Kí ló yẹ kó o ṣe kí ẹ̀mí lílágbára yìí má bàa máa darí rẹ?
Kà nípa bí Bíbélì ṣe fòpin sí èròǹgbà ọkùnrin kan tó ń wá ọ̀nà lójú méjèèjì láti pa àwọn kan nítorí pé ó fẹ́ gbẹ̀san.
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ àti òkè: Photo by Josh Mathes, Collection of the Supreme Court of the United States
Gerken/Naturfoto-Online.de