Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 8, 2004
Ǹjẹ́ Ẹ̀tanú Máa Dópin Láé?
Ẹ̀tanú máa ń pín àwọn èèyàn níyà ó sì ti yọrí sí ogun lónírúurú. Báwo la ṣe lè rẹ́yìn ẹ̀tanú títí láé fáàbàdà?
8 Ìgbà kan Ń Bọ̀ Tí Kò Ní Sí Ẹ̀tanú Mọ́
12 Mímú Òtítọ́ Bíbélì Dé Ọ̀dọ̀ Àwọn Kúrékùré
13 Àwọn Bàbá Tó Wà bí Aláìwà Ń Pọ̀ Sí I
18 Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Tó Dáa
22 Bíbélì Geneva Ìtumọ̀ Bíbélì Táráyé Ti Gbàgbé
27 “Ìgbà Wo Lo Máa Ráyè Ka Gbogbo Èyí Tán?”
30 Àwọn Èwe Tí Wọn Ò Fi Ìgbàgbọ́ Wọn Bò
32 Ẹ Káàbọ̀ sí Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Bá Ọlọ́run Rìn”
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó? 24
Àtẹ̀yìnbọ̀ ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó kì í dára rárá. Báwo làwọn ọ̀dọ́ ṣe lè yẹra fún un kí wọ́n má bàa kó sínú ìṣòro tó máa ń fà?
Ṣé Ìkọ̀sílẹ̀ Ló Máa Yanjú Ìṣòro Yín? 28
Àwọn ìgbésẹ̀ wo lẹ lè gbé kí ìgbéyàwó yín má bàa tú ká?
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 2, 3]
Àárín gbùngbùn Tamil Nadu, Íńdíà
Àwọn ọmọ tí wọ́n ta nù láwùjọ ní ilé ẹ̀kọ́ kan tó wà lábúlé
[Credit Line]
© Mark Henley/Panos Pictures