ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g05 4/8 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2005
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ìṣòro Wo Ló Ń Bá Àwọn Ọ̀dọ́ Fínra?
    Jí!—2009
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Rìn ní Ọ̀nà Tó Wu Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Báwo Ni Ìsìn Ṣe Ń Jẹ Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́kàn Tó?
    Jí!—1998
  • Àràmàǹdà Kàlẹ́ńdà Táwọn Máyà Fi Ń Ka Ọjọ́
    Jí!—2005
Àwọn Míì
Jí!—2005
g05 4/8 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

April 8, 2005

Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Kó sí Ìṣòro Lọ́wọ́

Ọ̀pọ̀ àgbà ọ̀jẹ̀ nínú ìwádìí ló ń sọ pé ìṣòro àwọn ọ̀dọ́ òde ìwòyí pọ̀ gàn-an ni. Ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ yìí á ṣàlàyé díẹ̀ lára ohun tó ń fà á táwọn ọ̀dọ́ fi ń kó sí pákáǹleke á sì fáwọn ọ̀dọ́ àtàwọn òbí nímọ̀ràn tó lè ràn wọ́n lọ́wọ́.

3 Nǹkan Ò Rọrùn Fáwọn Ọ̀dọ́

5 Wàhálà Tó Ń Báwọn Ọ̀dọ́ Òde Ìwòyí Fínra

9 Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Òde Ìwòyí Lọ́wọ́

12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

13 Àwọn Àǹfààní Tá À Ń Rí Lára Òkè

15 Mìmì Ti Ń Mi Àwọn Òkè Báyìí O

21 Ta Ló Máa Gba Àwọn Òkè Lọ́wọ́ Ewu?

25 “Ṣé Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Lè Yí Padà?”

28 Wíwo Ayé

30 Àwọn Ọmọdé Tó Ń Wo Ìwòkuwò

31 Àràmàǹdà Kàlẹ́ńdà Táwọn Máyà Fi Ń Ka Ọjọ́

32 Sún Mọ́ Ẹlẹ́dàá

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Mọ Iṣẹ́ Ọwọ́ Ṣe? 22

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ka iṣẹ́ ọwọ́ sí iṣẹ́ tí kì í dùn mọ́ọ̀yàn. Ṣùgbọ́n yálà o mọ̀ tàbí o kò mọ̀, oríṣiríṣi ọ̀nà ni iṣẹ́ ọwọ́ lè gbà ṣàǹfààní fún ẹ.

Ṣé Ọlọ́run Fọwọ́ sí Kí Ọkùnrin àti Ọkùnrin Máa Fẹ́ra? 26

Ọ̀rọ̀ yìí ti fa awuyewuye tó pọ̀. Àmọ́, ìlànà tó ṣe kedere wo ni Bíbélì fúnni lórí ọ̀ràn náà?

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]

Fọ́tò tí Chris Hondros/Getty Images yà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́