Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July-Septemer 2006
Bí Ìgbéyàwó Ẹni Ṣe Lè Láyọ̀
Lóde òní, ọ̀pọ̀ ogun tó ń jà nínú ìgbéyàwó kì í jẹ́ kó fìdí múlẹ̀. Wo ohun tó o lè ṣe láti mú kí ìgbéyàwó rẹ lágbára nípa títẹ̀ lé àwọn ìlànà tó lè ràn ọ́ lọ́wọ́ táá sì mú kí ìgbéyàwó rẹ láyọ̀ títí dọjọ́ alẹ́.
3 Ṣé Ìjì Tó Ń Jà Yìí Ò Ní Í Gbé Ìgbéyàwó Lọ?
6 Béèyàn Ṣe Lè Láyọ̀ Nínú Ìgbéyàwó
19 Ǹjẹ́ O Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Hẹ́gẹhẹ̀gẹ Ọjọ́ Ogbó?
23 Báwo Lo Ṣe Máa Pẹ́ Tó Láyé?
32 Ṣé Ó Ṣeé Ṣe Kí Ayọ̀ Jọba Nínú Ìdílé?
Kí Nìdí Tó Fi Pọn Dandan fún Mi Láti Máa Kàwé? 10
Gbọ́ ohun táwọn ọ̀dọ́ láti orílẹ̀-èdè mọ́kànlá sọ nígbà tá a bi wọ́n léèrè nípa ohun tó ń mú kó ṣòro fún wọn láti máa kàwé àtàwọn àǹfààní tí wọ́n ti rí látinú kíkàwé.
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná? 13
Ó rọrùn féèyàn láti náwó kọjá agbára ẹ̀. Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti máa gbéṣirò lé bó o ṣe ń náwó?