Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April-June 2008
Ṣé Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn La Wà Yìí?
Kí ni gbólóhùn náà, “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn,” tó wà nínú Bíbélì túmọ̀ sí? Báwo làwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ láwọn ọjọ́ ìkẹyìn ṣe kàn wá lẹ́nì kọ̀ọ̀kan? Ṣé ìrètí wà pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa?
8 Lẹ́yìn Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Ńkọ́?
25 Bó o Ṣe Lè Wá Ìsìn Tòótọ́ Rí
30 Wíwo Ayé
32 Báwọn Èwe Ṣe Lè Ṣẹ́pá Ìsoríkọ́
Ǹjẹ́ Gbígba Ohun Asán Gbọ́ Bá Ohun Tí Bíbélì Fi Kọ́ni Mu? 12
Ojú wo làwọn Kristẹni àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ fi wo ìgbàgbọ́ nínú ohun asán? Báwo lèèyàn ṣe lè jáwọ́ nínú irú ìgbàgbọ́ bẹ́ẹ̀?
Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Ò Fi Fọkàn Tán Mi? 22
Kí làwọn ọ̀dọ́ lè ṣe táwọn òbí á fi máa fọkàn tán wọn, tí wọ́n á sì máa fọ̀wọ̀ wọ̀ wọ́n?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 3]
© Fọ́tò Jacob Silberberg/Panos