ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g 4/09 ojú ìwé 31
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
  • Jí!—2009
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ni Kò Tọ̀nà Nínú Àwòrán Yìí?
  • Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí
  • Kí Lo Mọ̀ Nípa Àwọn Wòlíì?
  • ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2008
  • Ọlọ́run Kórìíra Ìwà Ìrẹ́jẹ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2010
  • Àtúnyẹ̀wò fún Ìdílé
    Jí!—2010
Àwọn Míì
Jí!—2009
g 4/09 ojú ìwé 31

Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?

Kí Ni Kò Tọ̀nà Nínú Àwòrán Yìí?

Ka Jóṣúà 2:15-18; 6:15-21; 7:1, 20, 21. Wo àwòrán yìí. Àwọn nǹkan wo ni kò tọ̀nà nínú àwòrán náà? Kọ ìdáhùn rẹ sórí àwọn ìlà yìí.

1. ․․․․․

2. ․․․․․

3. ․․․․․

4. ․․․․․

FÚN ÌJÍRÒRÒ:

Báwo ló ti ṣe pàtàkì tó pé ká má máa mú nǹkan tí kì í ṣe tiwa?

Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí

Dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀nyí, kó o sì kọ (àwọn) ẹsẹ Bíbélì tó yẹ sínú àlàfo.

OJÚ ÌWÉ 14 Kí ni ìgbéyàwó gbọ́dọ̀ ni lójú gbogbo èèyàn? Hébérù 13:․․․

OJÚ ÌWÉ 14 Lẹ́yìn tí ìfẹ́ ọkàn bá ti lóyún, kí ló máa ń bí? Jákọ́bù 1:․․․

Kí Lo Mọ̀ Nípa Àwọn Wòlíì?

Ka 2 Kíróníkà 18:1-19:3. Lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀nyí.

5. ․․․․․

Kí lorúkọ wòlíì tí Ọba Áhábù kórìíra?

6. ․․․․․

Kí nìdí tí Áhábù fi kórìíra wòlíì náà?

7. ․․․․․

Kí ni wòlíì náà sọ fún Áhábù, kí ni Áhábù sì ṣe?

FÚN ÌJÍRÒRÒ:

Ìgbà wo ló yẹ kó o lo ìgboyà bíi ti wòlíì yìí?

ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ

1. Àwọn ògiri Jẹ́ríkò wó lulẹ̀ bẹẹrẹbẹ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó kọ lu ìlú náà.

2. Okùn tí Ráhábù so mọ́ fèrèsé kì í ṣe aláwọ̀ búlúù, aláwọ̀ rírẹ̀dòdò ni.

3. Kì í ṣe ère ni Ákáánì jí, bí kò ṣe ẹ̀wù kan, wúrà gbọọrọ kan àti ṣékélì fàdákà.

4. Kì í ṣe alẹ́ ni wọ́n gbéjà kò wọ́n.

5. Mikáyà.

6. Ó kéde àwọn ìdájọ́ Jèhófà sórí Áhábù.

7. Pé Áhábù máa ṣubú lójú ogun. Áhábù ni kí wọ́n ju Mikáyà sí àtìmọ́lé.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́