ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g 10/09 ojú ìwé 31
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
  • Jí!—2009
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ni Kò Sí Nínú Àwòrán Yìí?
  • Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí
  • Kí Lo Mọ̀ Nípa Bárákì Onídàájọ́?
  • ÌDÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ
  • Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé
    Jí!—2011
  • Àtúnyẹ̀wò fún Ìdílé
    Jí!—2010
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2010
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2009
Àwọn Míì
Jí!—2009
g 10/09 ojú ìwé 31

Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?

Kí Ni Kò Sí Nínú Àwòrán Yìí?

Ka Ìṣe 5:1-5. Wo àwòrán yìí. Àwọn nǹkan wo ni kò sí nínú àwòrán náà? Kọ ìdáhùn rẹ sórí àwọn ìlà yìí, kó o ya èyí tó kù lára àwòrán náà, kó o sì kùn ún.

1. ․․․․․

2. ․․․․․

FÚN ÌJÍRÒRÒ:

Kí lo rò pé ó fà á tí Ananíà fi purọ́? Ẹ̀kọ́ wo lo rí kọ́ nínú àkọsílẹ̀ náà?

Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí

Dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀nyí, kó o sì kọ (àwọn) ẹsẹ Bíbélì tó yẹ sínú àlàfo.

OJÚ ÌWÉ 27 Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí ọkàn tó bá dẹ́ṣẹ̀? Ìsíkíẹ́lì 18:․․․

OJÚ ÌWÉ 27 Kí làwọn òkú mọ̀? Oníwàásù 9:․․․

OJÚ ÌWÉ 19 Kí ni gbogbo wa máa ń ṣe lọ́pọ̀ ìgbà? Jákọ́bù 3:․․․

OJÚ ÌWÉ 19 Kí ló yẹ kó o mú kúrò lọ́dọ̀ rẹ? Éfésù 4:․․․

Kí Lo Mọ̀ Nípa Bárákì Onídàájọ́?

Ka Onídàájọ́ 4:1-24. Lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀nyí.

3. ․․․․․

Ta ni wòlíì obìnrin tó ràn án lọ́wọ́?

4. ․․․․․

Lọ́wọ́ ọba ilẹ̀ Kénáánì wo ló ti gba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀?

5. ․․․․․

Òótọ́ àbí irọ́? Jóṣúà gbé láyé ṣáájú Bárákì Onídàájọ́.

FÚN ÌJÍRÒRÒ:

Ipa wo làwọn obìnrin kó nínú báwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ṣẹ́gun àwọn ará Kénáánì? Ipa pàtàkì wo làwọn obìnrin ń kó nínú ìjọsìn Ọlọ́run lónìí?

ÌDÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ

1. Kò sí owó lọ́wọ́ Ananíà.

2. Kò sí àpọ́sítélì Pétérù nínú àwòrán náà.

3. Dèbórà.—Onídàájọ́ 4:4-8.

4. Jábínì.—Onídàájọ́ 4:2.

5. Òótọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́