Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April–June 2010
Ṣé Ìkọ̀sílẹ̀ Ló Wá Kàn?
Bí àárín ọ̀pọ̀ tọkọtaya kò bá gún, kì í pẹ́ rárá tí wọ́n fi máa ń kọra wọn sílẹ̀. Àmọ́, ṣé ìkọ̀sílẹ̀ bọ́gbọ́n mu? Àwọn ìṣòro míì wo ni ìkọ̀sílẹ̀ máa ń mú wá láfikún sí ìṣòro ìṣúnná owó? Ju gbogbo ẹ̀ lọ, kí làwọn tọkọtaya tí àárín wọn kò gún lè ṣe tí ìgbéyàwó wọn ò fi ní tú ká?
4 Ohun Mẹ́rin Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀
8 Kí Lẹ Lè Ṣe Tí Ìgbéyàwó Yín Ò Fi Ní Tú Ká?
27 Jẹ́ Ká Lọ sí Ọjà Kan Nílẹ̀ Áfíríkà
32 Jésù Fi Ẹ̀mí Rẹ̀ Lélẹ̀ fún Ọ̀pọ̀ Èèyàn
Ṣé Gbogbo Ìwé Inú Bíbélì Ṣì Wúlò Lóde Òní? 14
Kà nípa bí kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tó wà nínú Òfin Mósè, tó fi mọ́ àkọsílẹ̀ àwọn ìtàn ìlà ìdílé tó wà nínú Bíbélì ṣe wúlò fún wa lóde òní.
Kí Nìdí Táwọn Ọkùnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? 24
Irú àwọn obìnrin wo gan-an ló máa ń wu àwọn ọkùnrin? Ìdáhùn ìbéèrè yìí lè yà ẹ́ lẹ́nu!