ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g20 No. 3 ojú ìwé 16
  • Wọ́n Borí Ìkórìíra

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọ́n Borí Ìkórìíra
  • Jí!—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn
    Jí!—2020
  • Mo Fẹ́ Jà fún Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn
    Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
  • Ohun Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́
    Jí!—2020
  • “Èyí Mà Rọrùn Gan-an O!”
    Jí!—2016
Àwọn Míì
Jí!—2020
g20 No. 3 ojú ìwé 16

Wọ́n Borí Ìkórìíra

Wàá rí ìtàn àwọn èèyàn yìí àtàwọn míì lórí ìkànnì jw.org.

Wọ́n di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́

Johny àti Gideon ń kí àwọn ọmọdé níwájú ilé ìpàdé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀yà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni Johny àti Gideon, tí wọ́n sì wà nínú ẹgbẹ́ òṣèlú ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ nígbà kan, ní báyìí wọ́n ti di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́.

Wo fídíò Johny àti Gideon: Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Wọ́n Ti Di Arákùnrin Báyìí. Wá fídíò náà lórí ìkànnì jw.org.

“Mo Fẹ́ Jà fún Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn”

Rafika Morris.

Obìnrin kan tó ń jẹ́ Rafika dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ajìjàgbara láti gbógun ti kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà àti ìwà ìrẹ́jẹ. Àmọ́ nígbà tó lọ sí àpéjọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, ó wá rí ìṣọ̀kan tó ti ń wá tipẹ́.

Wo fídíò Rafika Morris: Mo Fẹ́ Jà fún Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn. Wá fídíò náà lórí ìkànnì jw.org.

Wọ́n borí ìkórìíra

Collage: 1. Ọmọ Árábù kan àti Júù kan ń bára wọn sọ̀rọ̀ bí wọ́n ṣe jọ ń rìn lọ. 2. Júù kan wà pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀, ó ń rẹ́rìn-ín.

Kí ló mú kí ọmọ Árábù kan àti Júù kan borí ẹ̀mí ìkórìíra?

Wo fídíò Ìgbà Wo Ni Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Máa Ṣẹ́gun Ìkórìíra? Wá fídíò náà lórí ìkànnì jw.org.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́