ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g20 No. 2 ojú ìwé 16
  • Ohun Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́
  • Jí!—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Míì Tó Máa Ran Ìdílé Lọ́wọ́
    Jí!—2018
  • Wàá Rí Ìmọ̀ràn Tó Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lórí Ìkànnì JW.ORG
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Òbí
    Jí!—2019
  • Ìkànnì Wa Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì—Ó Wúlò Fún Àwa Àtàwọn Ẹlòmíì
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
Àwọn Míì
Jí!—2020
g20 No. 2 ojú ìwé 16
Obìnrin kan jókòó sórí àga, ọkàn ẹ̀ balẹ̀, ó ń ka Bíbélì.

Ohun Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́

Ṣé èèyàn rẹ kan kú ni?

  • Lọ sórí ìkànnì jw.org, kó o sì wá “Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀.”

Ṣé ọrọ̀ ajé rẹ ti dẹnu kọlẹ̀?

  • Lọ sórí ìkànnì jw.org, kó o sì wá “Máa Fọgbọ́n Náwó.”

Ṣé o ti béèrè rí pé, ‘Kí ni mò ń ṣe láyé?’

  • Lọ sórí ìkànnì jw.org, kó o sì wá “má ṣe jẹ́ káyé sú ẹ” àti “ayé rẹ ṣì máa dùn!”

Ṣé àìsàn tí ò lọ bọ̀rọ̀ ló ń bá ẹ fínra?

  • Lọ sórí ìkànnì jw.org, kó o sì wá “bí àwọn ìdílé ṣe lè kojú ìṣòro àìsàn bára kú.”

Inú Bíbélì lo ti lè rí ìtọ́sọ́nà tó dáa jù lọ nípa bí ẹnì kọ̀ọ̀kan nínú ìdílé ṣe lè gbé ìgbé ayé tó dára gan-an. Àwọn ìlànà Bíbélì á jẹ́ kó o túbọ̀ máa ronú dáadáa kó o sì ṣèpinnu tó bọ́gbọ́n mu.​—ÒWE 1:1-4.

A rọ̀ ẹ́ pé kó o kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì fúnra rẹ. Wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́