ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • bt ojú ìwé 156
  • Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”
  • “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Kí Nìdí Tí Iṣẹ́ Ìwàásù Ilé-dé-Ilé Fi Ṣe Pàtàkì Nísinsìnyí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ẹ Maa Kọni ni Gbangba ati Lati Ile De Ile
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • “Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
“Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
bt ojú ìwé 156
Pọ́ọ̀lù ń wàásù fún ọ̀pọ̀ èèyàn níbi ọjà ìlú Éfésù, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn míì ń bá káràkátà wọn lọ.

APÁ 7 • ÌṢE 18:23–21:17

Wọ́n ń kọ́ni “Ní Gbangba Àti Láti Ilé Dé Ilé”

ÌṢE 20:20

Kí nìdí tá a fi gbọ́dọ̀ jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, ká sì máa mú ọ̀rọ̀ wa bá ipò onírúurú èèyàn tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ mu? Ọ̀nà pàtàkì wo la gbà ń wàásù ìhìn rere? Báwo la ṣe lè fi hàn pé ó ṣe pàtàkì ká máa ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ju ká tẹ́ ara wa lọ́rùn lọ? A máa rí ìdáhùn àwọn ìbéèrè pàtàkì yìí nínú àkọsílẹ̀ tó ń múnú ẹni dùn nípa ìrìn àjò míṣọ́nnárì ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí Pọ́ọ̀lù rìn kẹ́yìn.

Arákùnrin kan ń wàásù fún obìnrin kan níbi táwọn èèyàn ti ń wọkọ̀ ojú irin.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́