ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • bt ojú ìwé 84
  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”
  • “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù” (Ìṣe 5:28)
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • ‘Wọ́n Wàásù Ìjọba Ọlọ́run Láìsí Ìdíwọ́’
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • “Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
“Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
bt ojú ìwé 84
Àwọn alátakò tínú ń bí wọ́ Bánábà lọ sí ẹ̀yìn odi ìlú Áńtíókù ti Písídíà.

APÁ 4 • ÌṢE 13:1–14:28

‘Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde’

ÌṢE 13:4

Nínú apá yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìrìn àjò míṣọ́nnárì àkọ́kọ́ tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù lọ. Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo ìlú tí Pọ́ọ̀lù dé ni wọ́n ti ṣenúnibíni sí i. Síbẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ ń ran Pọ́ọ̀lù lọ́wọ́ kó lè máa bá a lọ láti máa wàásù, ó sì ń dá àwọn ìjọ tuntun sílẹ̀. Bá a ṣe ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìtàn tó gbádùn mọ́ni yìí, ó dájú pé ó máa wu àwa náà pé ká fìtara ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.

Àwọn èèyàn tínú ń bí halẹ̀ mọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Kánádà lọ́dún 1945.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́