ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • bt ojú ìwé 180
  • ‘Wọ́n Wàásù Ìjọba Ọlọ́run Láìsí Ìdíwọ́’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Wọ́n Wàásù Ìjọba Ọlọ́run Láìsí Ìdíwọ́’
  • “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù” (Ìṣe 5:28)
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • “Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Inúnibíni Tó Lágbára Sí Ìjọ”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • “Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè . . . Gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
“Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
bt ojú ìwé 180
Ìbátan Pọ́ọ̀lù ń bá Kíláúdíù Lísíà sọ̀rọ̀.

APÁ 8 • ÌṢE 21:18–28:31

‘Wọ́n Wàásù Ìjọba Ọlọ́run Láìsí Ìdíwọ́’

ÌṢE 28:31

Nínú apá yìí, a máa rí bí àwọn jàǹdùkú ṣe gbéjà ko àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù, bí wọ́n ṣe mú un lọ sẹ́wọ̀n, bó ṣe fara dà á nígbà tó wà lẹ́wọ̀n àti bó ṣe jẹ́jọ́ níwájú oríṣiríṣi àwọn aláṣẹ Róòmù. Síbẹ̀, kò yéé wàásù nípa Ìjọba Ọlọ́run. Bó o ṣe ń ṣàyẹ̀wò apá tó wúni lórí tó gbẹ̀yìn ìwé Ìṣe, máa bi ara ẹ pé, ‘Báwo ni mo ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ajíhìnrere tó nígboyà, tó sì ń fìtara wàásù yìí?’

Àwòrán yìí ṣàfihàn ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà tí wọ́n fòfin de iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà láwọn ọdún 1940. Ọmọkùnrin tó wà lórí kẹ̀kẹ́ yìí ń fọgbọ́n wo àyíká bó ṣe ń kó àwọn ìwé tó ṣàlàyé Bíbélì lọ sí ilé arákùnrin kan.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́