ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sn orin 7
  • Ìyàsímímọ́ Kristẹni

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìyàsímímọ́ Kristẹni
  • Kọrin sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìyàsímímọ́ Kristẹni
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Ìyàsímímọ́—Fún Ta Ni?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ya Ara Rẹ Sí Mímọ́ Fún Jèhófà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ẹ Yin Jèhófà, Ọlọ́run Wa!
    Kọrin sí Jèhófà
Àwọn Míì
Kọrin sí Jèhófà
sn orin 7

Orin 7

Ìyàsímímọ́ Kristẹni

Bíi Ti Orí Ìwé

(Hébérù 10:7, 9)

1. Torí Jèhófà ti ṣẹ̀dá

Ọ̀run àtayé yìí,

Tirẹ̀ nilẹ̀ àti ọ̀run,

Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni.

Ó fún wa ní èémí ìyè

Ẹ̀dá rẹ̀ sì wá ríi

Pé òun ni ìyìn àtìjọsìn

Gbogbo yẹ kó jẹ́ tirẹ̀.

2. Jésù Kristi ṣèrìbọmi

Láti módodo ṣẹ.

Ó gbàdúrà s’Ọ́lọ́run pé:

‘Mo dé wá ṣèfẹ́ rẹ.’

Ó jáde lódò Jọ́dánì

Gẹ́gẹ́ b’áyànfẹ́ Jáà,

Ó fìgbọràn òun òtítọ́ sìn

Bí Ìránṣẹ́ Ọlọ́run.

3. ’Wájú rẹ la wá Jèhófà,

A ńyin oókọ ńlá rẹ.

Ayé wa la yà sí mímọ́

Pẹ̀lú ’rẹ̀lẹ̀ ọkàn.

O yọ̀ǹda Ọmọ bíbí rẹ,

Tó san gbèsè ńlá náà.

Bí a kú tàbí a wà láàyè,

Tìrẹ laó máa jẹ́ títí.

(Tún wo Mát. 16:24; Máàkù 8:34; Lúùkù 9:23.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́