ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sn orin 121
  • Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí
  • Kọrin sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Máa Gba Ara Yín Níyànjú
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • “Ẹ Máa Fún Ara Yín Níṣìírí, Kí Ẹ sì Máa Gbé Ara Yín Ró”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Má Ṣe Kúrò Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • Ẹ Máa Ru Ara Yín Lọ́kàn Sókè Sí Ìfẹ́ àti Sí Àwọn Iṣẹ́ Àtàtà—Báwo?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
Àwọn Míì
Kọrin sí Jèhófà
sn orin 121

Orin 121

Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí

Bíi Ti Orí Ìwé

(Hébérù 10:24, 25)

1. Báa ti ńfún ara wa níṣìírí

Ká lè jọ máa sin Jèhófà,

Ìdè ìfẹ́ wa ńlágbára síi;

Iṣẹ́ rere ńbí àlàáfíà.

Ìfẹ́ àárín àwa Kristẹni

Ló ńjẹ́ ká lè nífaradà.

Ibi ààbò ni ìjọ wa jẹ́,

Ọkàn wa máa ńbalẹ̀ níbẹ̀.

2. Ọ̀rọ̀ táa sọ lákòókò tó yẹ

Mà ńtuni lára púpọ̀ o!

Ọ̀rọ̀ ìtùnú bẹ́ẹ̀ la máa ńgbọ́

Lẹ́nu àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́.

Ó mà dára ká máa ṣiṣẹ́ pọ̀o

Àwa tírètí wa jọra!

A máa ń fún ara wa lókun,

A ńjùmọ̀ gbẹ́rù tó wúwo.

3. Bí a ṣe ńfojú ìgbàgbọ́ ríi

Tọ́jọ́ Jèhófà ńsún mọ́lé,

A gbọ́dọ̀ máa pàdé pọ̀ déédéé

Ká lè máa rìn lọ́nà ìyè.

Báa ṣe ńfìṣọ̀kan sin Jèhófà,

A fẹ́ máa sìnín títí ayé.

A jọ ńfún ara wa níṣìírí

Ká lè pa ìwà títọ́ mọ́.

(Tún wo Lúùkù 22:32; Ìṣe 14:21, 22; Gál. 6:2; 1 Tẹs. 5:14.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́