ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ll apá 2 ojú ìwé 6-7
  • Ta Ni Ọlọ́run Tòótọ́?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ta Ni Ọlọ́run Tòótọ́?
  • Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Apa 2
    Tẹ́tí sí Ọlọ́run
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Awọn Ẹmi Ko Gbe Ki Wọn si Kú Rí Lori Ilẹ Aye
    Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha wa Niti Gidi Bi?
  • Ta Ni Ọlọ́run?
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
Àwọn Míì
Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
ll apá 2 ojú ìwé 6-7

APÁ 2

Ta Ni Ọlọ́run Tòótọ́?

Látorí ìtẹ́ rẹ̀, Jèhófà ń wo àwọn ohun tó dá sí ọ̀run àti ayé

Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo ló wà, orúkọ rẹ̀ ni Jèhófà. (Sáàmù 83:18) Ẹ̀mí ni; a kò lè fi ojú rí i. Ó nífẹ̀ẹ́ wa, ó sì fẹ́ kí àwa náà nífẹ̀ẹ́ òun. Bákan náà, ó fẹ́ ká nífẹ̀ẹ́ àwọn ẹlòmíì. (Mátíù 22:35-40) Òun ni Ẹni Gíga Jù Lọ, òun sì ni Ẹlẹ́dàá ohun gbogbo.

Ẹ̀dá ẹ̀mí kan tó lágbára ni Ọlọ́run kọ́kọ́ dá, òun la wá mọ̀ sí Jésù Kristi. Jèhófà tún dá àwọn áńgẹ́lì.

Jèhófà ló dá ohun gbogbo tó wà ní ọ̀run . . . àti lórí ilẹ̀ ayé. Ìfihàn 4:11

Jèhófà Ọlọ́run ló dá àwọn ìràwọ̀ àti ayé pẹ̀lú ohun gbogbo tó wà nínú rẹ̀.​—Jẹ́nẹ́sísì 1:1.

Ó fi erùpẹ̀ ilẹ̀ dá Ádámù, ọkùnrin àkọ́kọ́.​—Jẹ́nẹ́sísì 2:7.

  • Kí nìdí tó fi yẹ ká máa bọlá fún Jèhófà?​—Àìsáyà 42:5.

  • Kí ni díẹ̀ lára àwọn ànímọ́ tí Ọlọ́run ní?​—Ẹ́kísódù 34:6.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́