ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ll apá 10 ojú ìwé 22-23
  • Àwọn Ìbùkún Wo Ni Àwọn Tó Bá Tẹ́tí sí Ọlọ́run Máa Rí Gbà?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìbùkún Wo Ni Àwọn Tó Bá Tẹ́tí sí Ọlọ́run Máa Rí Gbà?
  • Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Apa 10
    Tẹ́tí sí Ọlọ́run
  • “Wò ó! Mo Ń Sọ Ohun Gbogbo Di Tuntun”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Àwọn Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run Yóò Gbé Inú Párádísè
    Ìwọ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run!
  • Kí Ni Ète Ọlọrun fún Ilẹ̀ Ayé?
    Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
Àwọn Míì
Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
ll apá 10 ojú ìwé 22-23

APÁ 10

Àwọn Ìbùkún Wo Ni Àwọn Tó Bá Tẹ́tí sí Ọlọ́run Máa Rí Gbà?

Ọlọ́run máa jí èyí tó pọ̀ jù lára àwọn tó ti kú dìde sí ayé. Ìṣe 24:15

Àwọn èèyàn ń kí àwọn tó jíǹde nínú Párádísè

Ronú nípa àwọn ìbùkún tí o máa gbádùn lọ́jọ́ iwájú tí o bá tẹ́tí sí Jèhófà! Wàá ní ìlera pípé, ẹnì kankan ò ní ṣàìsàn mọ́. Àwọn èèyàn burúkú ò ní sí mọ́, wàá sì lè fọkàn tán gbogbo èèyàn.

Kò ní sí ìrora, ìbànújẹ́ àti ẹkún mọ́. A ò ní darúgbó mọ́, a ò sì ní kú mọ́.

Àwọn ọ̀rẹ́ àti àwọn mọ̀lẹ́bí ló máa yí ọ ká. Párádísè máa dùn-ún gbé gan-an ni.

Kò ní sí ìbẹ̀rù. Inú àwọn èèyàn máa dùn gan-an.

Ìjọba Ọlọ́run máa fòpin sí gbogbo ìyà tó ń jẹ aráyé. Ìfihàn 21:​3, 4

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́