ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mb ẹ̀kọ́ 2
  • Ẹ̀kọ́ 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀kọ́ 2
  • Ẹ̀kọ́ Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀kọ́ Bíbélì
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Èèyàn Mẹ́jọ La Ìparun Já
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Àwọn Ọmọdé Ha Wà Láìséwu Lọ́dọ̀ Ajá Rẹ bí?
    Jí!—1997
  • Nóà Kan Ọkọ̀ Áàkì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ẹ̀kọ́ Bíbélì
mb ẹ̀kọ́ 2

Ẹ̀kọ́ 2

Jẹ́nẹ́sísì 7:7-10; 8:15-17

Wo àwọn ẹranko tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọkọ̀ Nóà.

Èwo ló máa ń ké mùúù, èwo ló máa ń gbó?

Gbogbo ẹranko, àwọn tó kéré àtàwọn tó tóbi, ọkọ̀ áàkì gba gbogbo wọn là.

IṢẸ́ ÒBÍ

Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:

Jẹ́nẹ́sísì 7:7-10; 8:15-17

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Béárì Ajá Erin

Àgùnfọn Kìnnìún Ọ̀bọ

Ẹlẹ́dẹ̀ Àgùntàn

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà Òṣùmàrè

Ké bí àwọn ẹranko yìí ṣe ń ké:

Ajá Kìnnìún Ọ̀bọ

Ẹlẹ́dẹ̀ Àgùntàn

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 6, 7]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́